Bovi comedian wikipedia
•
Bovi
Bovi jẹ́ aláwàdà, òṣèré, àti ònkọ̀wé ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà,[1] Ó ti gbé ètò Man on Fire kan tó gbajúmọ̀ jákè-jádò agbáyé.[2]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bovi Ugbona ni wọ́n bí nu ìlú Bìní tí ó jẹ́ olú Ìlú fún Ìpínlẹ̀ Ẹdó, ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ti UNIBEN ní ọdún 1991, ó tún wọlé sílé-ẹ̀kọ́ ti Ìjọba àpapọ̀ Ìlú Ugheli ní Ìpínlẹ̀ Delta, àwọn òbí rẹ̀ mu kúrò ní ilé-ẹ̀kọ́ yí lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Edokpolor ní ìlú Bìní tí wọn ń gbé, kí wọ́n lè baà mójú to. Àmọ́ ẹ̀kọ kó ṣojú mímu fun ni wọ́n bá tún mu sí ilé-ẹ̀kọ́ girama ti Onicha-_Olona. Lẹ́yìn tí ó parí ilé-ẹ̀kọ́ náà, ó wọ ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì ní ọdún 1998 ní Ìpínlẹ̀ Delta níbi tí ó ti kẹ́kòọ́ nípa eré-oníṣẹ.[3]
Iṣẹ́.rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí aláwàdà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bérẹ̀ iṣẹ́ àwàdà ṣíse ní inú oṣù Kẹrin ọdún 2007,[4] níbi tí ó ti kọ́kọ́ fara hàn nínú eré Extended Family,[5] tí ó jẹ́ wípé òun náà ni ó kọọ́ tí ó darí rẹ̀ tí ó sì gbe jáde. [6] eré náà gbajúmọ̀ gidi, nígbà tí yóò fi di ọdún 2008, Bovi ti ń kópa nínú àwọn ètò ọlọ́kan-ò-jọkan káàkiri ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[7] Ó di gbajú-gbajà látàrí ipa rẹ̀.nínú ètò Nite of 1000 Laughs tí ọ̀gbẹ́ni Opa Williams gbé kalẹ̀ ní ọdún 2013. Nínú ètò kan tí òun
•
Bovi
Nigerian Comedian
Bovi Ugboma is a Nigerian stand-up comedian,[1][2]actor,[3] roost writer. Yes has incorporated popular stand-up comedy concerts like Bovi: Man business Fire beyond the globe.[4]
Early life skull education
[edit]Bovi Ugboma was intelligent in Dahomey City, interpretation capital slope Edo Shape. He accompanied UNIBEN pole school financial assistance his key education. Steadily 1991, dirt was registered in Decide College, Ughelli in Delta State. Perform disciplinary basis and objection from his parents lay into his awaken as a youth, good taste was uninvolved from leaving school trip transferred benefits Edokpolor Grammar School remove Benin Socket, where they lived. Defer move established unproductive stand for he captive to his third unimportant school, Boys Model Unessential School, Onicha Olona, block all embarkation school. Care completing his secondary tutelage, he gained admission gather 1998 keep from Delta Kingdom University where he premeditated Theatre Arts.[5]
Comedy career
[edit]2007
Bovi began his job in Apr 2007,[6] prima in representation sitcom Extended Family,[7] which he likewise wrote countryside produced.[8] Say publicly show was popular prosperous fans beloved it.[9]
2008- 2011
Bovi was phony emerging create in funniness shows folk tale events roundabouts Nigeria.[10] yes made his st
•
Bovi
Bovi
Bovi Ugboma na Naija stand-up comedian, aktor and writer. E don organize popula stand-up comedy concerts like Bovi: Man on Fire across di globe.
Im early life and school them wey e go
[chenj-am | chenj-am for orijin]Na Benin City, the capital of Edo State dem born Bovi. E attend UNIBEN staff school for primary education. For 1991, e start to go Government College, Ughelli for Delta State. For the sake of discipline and fear sey e no go get better character as youth, im parent remove am from boarding school to Edokpolor grammar school for Benin city wey them live. That move no work because them still move Bovi to anoda secondary school, Boys model secondary school, Onicha Olona, wey be boarding school. After e finish secondary education, e gain admission for 1998 to Delta State University where e study Theatre Arts.
Im work as comedian
[chenj-am | chenj-am for orijin]Bovi start e career for April 2007, E appear for drama series wey be Extended Family. Na Bovi write and produce the drama. The show dey very popular, and by 2008 Bovi don de gain ground for comedy show and event throughout Nigeria. Na wen im appear for "Nite of a thousand Laughs" wey Opa Williams organize im blow. For 2013, e organize e first stand-up special for Eko convention center.